ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

b Lọ́dún díẹ̀ lẹ́yìn náà, àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù kọ lẹ́tà sáwọn Hébérù, láti fi ṣàlàyé bí májẹ̀mú tuntun ti ṣe pàtàkì tó. Nínú lẹ́tà yẹn, ó jẹ́ kó ṣe kedere pé májẹ̀mú tuntun ti sọ májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá baba ńlá wọn dá di èyí tí kò bágbà mu mọ́. Ọ̀rọ̀ tí Pọ́ọ̀lù sọ yẹn fún ìgbàgbọ́ àwọn Kristẹni kan tí wọ́n ń rin kinkin mọ́ Òfin Mósè lókun, ó tún mú kó rọrùn fáwọn Júù tó di Kristẹni yẹn láti ṣàlàyé fáwọn tó ṣì ń tẹ̀ lé Òfin Mósè pé kò pọn dandan kéèyàn máa tẹ̀ lé òfin náà mọ́.​—Héb. 8:7-13.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́