Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Bíbélì NET (2005) kà pé: “Má ṣe jẹ́ kí ayé mú ẹ tẹ̀ sí ọ̀nà rẹ̀.” Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé tó wà níbẹ̀ sọ pé: “Ó ṣe kedere pé àwọn kan wo ọ̀rọ̀ náà ‘mú ẹ tẹ̀ sí’ tó wà nínú ẹsẹ yìí gẹ́gẹ́ bí ohun téèyàn ń ṣe láìfura. Ṣùgbọ́n, . . . déwọ̀n àyè kan, ó lè jẹ́ ohun téèyàn ń mọ̀ọ́mọ̀ ṣe. Àmọ́ ṣá, ó jọ pé ọ̀nà méjèèjì ni ayé gbà ń múni tẹ̀ sí ọ̀nà rẹ̀.”