Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Kò sí ọ̀rọ̀ Hébérù tó dúró fún gbólóhùn náà “àpọ́n” nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù ti ìpilẹ̀ṣẹ̀.