Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Bí ìbànújẹ́ kò bá kúrò lọ́kàn àwọn ọ̀dọ́ kan, wọ́n lè máa ronú pé àwọn á kúkú pa ara àwọn. Bí irú èrò yìí bá wá sí ẹ lọ́kàn, tètè fọ̀rọ̀ náà lọ àgbàlagbà kan tó o fọkàn tán.—Wo Orí 14 nínú ìwé yìí, fún àlàyé síwájú sí i.