Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e Nígbà míì, ìdààmú ọkàn tó pọ̀ gan-an máa ń bá àwọn tí wọ́n fipá bá lò pọ̀. Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ó máa dára kí wọ́n rí dókítà. Wo Orí 13 àti 14 nínú ìwé yìí, fún àlàyé síwájú sí i nípa bó o ṣe lè borí ìdààmú ọkàn.