Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Gbólóhùn tí ọ̀dọ́kùnrin náà lò túmọ̀ sí “ọmọ bélíálì (ìyẹn ẹni tí kò wúlò fún ohunkóhun).” Bí àwọn Bíbélì míì ṣe túmọ̀ ẹsẹ yìí ni pé Nábálì jẹ́ ọkùnrin “tí kì í fẹ́ gbọ́ ti ẹnikẹ́ni,” pé nípa bẹ́ẹ̀ “kò yẹ lẹ́ni téèyàn ń bá sọ̀rọ̀.”