Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kò pẹ́ sígbà tá à ń sọ yìí ni Jèhófà ní kí Èlíjà bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ Èlíṣà níṣẹ́ tó fi dẹni tí wọ́n mọ̀ sí “ẹni tí ń bu omi sí ọwọ́ Èlíjà.” (2 Ọba 3:11) Èlíṣà di ìránṣẹ́ Èlíjà tó ti dàgbàlagbà, ó ń bá a ṣe àwọn iṣẹ́ tó bá fẹ́ ṣe.