ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé áńgẹ́lì tó sọ “ọ̀rọ̀ Jèhófà” fún Èlíjà ní 1 Àwọn Ọba 19:9 náà ló tún sọ̀rọ̀ ní “ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́, rírẹlẹ̀” níbí. Ní ẹsẹ 15, Bíbélì pe áńgẹ́lì náà ní “Jèhófà.” Èyí lè mú wa rántí áńgẹ́lì tí Jèhófà ní kó máa tọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ́nà ní aginjù, ẹni tí Ọlọ́run sọ nípa rẹ̀ pé: “Orúkọ mi wà lára rẹ̀.” (Ẹ́kís. 23:21) Lóòótọ́, a kò lè sọ pàtó pé ẹni báyìí ni, àmọ́ Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé ṣáájú kí Jésù tó wá sí ayé, òun ni “Ọ̀rọ̀ náà,” ìyẹn Agbọ̀rọ̀sọ pàtàkì tí Jèhófà máa ń rán sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.—Jòh. 1:1.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́