ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a Nǹkan pàtàkì ló jẹ́ pé Jónà wá láti ìlú kan tó wà ní Gálílì. Torí nígbà tí àwọn Farisí ń sọ̀rọ̀ nípa Jésù, wọ́n fi ìgbéraga sọ pé: “Ṣe ìwádìí káàkiri, kí o sì rí i pé kò sí wòlíì kankan tí a óò gbé dìde láti Gálílì.” (Jòh. 7:52) Ọ̀pọ̀ àwọn atúmọ̀ èdè àtàwọn tó ń ṣèwádìí sọ pé ohun táwọn Farisí wọ̀nyẹn ń sọ ni pé kò tíì sí ẹni tó jẹ́ wòlíì rí láti àgbègbè Gálílì tí kò já mọ́ nǹkan kan, kò sì lè sí láé. Tó bá jẹ́ ohun tí àwọn Farisí náà ní lọ́kàn nìyẹn, a jẹ́ pé ṣe ni wọ́n gbójú fo ohun tí ìtàn àti àsọtẹ́lẹ̀ sọ.—Aísá. 9:1, 2.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́