ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

b Bíbélì Septuagint sọ pé Jónà hanrun láti fi sọ bó ṣe sùn wọra tó. Àmọ́, ká má kàn gbà pé Jónà ò bìkítà nípa ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ló ṣe lọ wábi sùn sí o. Ká rántí pé nígbà míì ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn máa ń jẹ́ kí oorun kunni. Nígbà tí Jésù wà nínú ìrora ní ọ̀gbà Gẹtisémánì, ńṣe ni Pétérù, Jákọ́bù àti Jòhánù “ń tòògbé nítorí ẹ̀dùn-ọkàn.”—Lúùkù 22:45.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́