Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tá a bá fi ohun tí àwọn èèyàn tó wà ní sínágọ́gù yìí ṣe lọ́jọ́ tí wọ́n fìtara pòkìkí Jésù pé ó jẹ́ wòlíì Ọlọ́run wé ohun tí wọ́n ṣe lọ́jọ́ kejì nígbà tí wọ́n ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ṣe kedere pé ọ̀rọ̀ wọn kò láyọ̀lé.—Jòh. 6:14.