Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Ẹnikẹ́ni tó bá di ẹni àmì òróró lẹ́yìn ikú èyí tó gbẹ̀yìn lára àwọn ẹni àmì òróró tó wà nínú àwùjọ àkọ́kọ́, ìyẹn àwùjọ tó rí “ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìroragógó wàhálà” lọ́dún 1914, kì í ṣe ara àwọn tí Jésù pè ní “ìran yìí.”—Mát. 24:8.