Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d Ní September 1920, wọ́n tẹ àkànṣe ìwé ìròyìn The Golden Age (tí à ń pè ní Jí! báyìí) jáde tó ṣe ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé nípa ọ̀pọ̀lọpọ̀ inúnibíni tó wáyé nígbà ogun, ní Kánádà, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Jámánì àti Amẹ́ríkà, tí òmíràn lára rẹ̀ sì burú jáì. Bẹ́ẹ̀ sì rèé, irú àwọn inúnibíni bẹ́ẹ̀ kò wọ́pọ̀ ní ogún ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ṣáájú Ogun Àgbáyé Kìíní.