Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ìwé ìwádìí kan sọ pé ọ̀rọ̀ Gíríìkì tí wọ́n pè ní “ṣamọ̀nà” nínú ẹsẹ yẹn túmọ̀ sí “fi ọ̀nà hanni.”