Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ní June 1880, ìwé ìròyìn Zion’s Watch Tower sọ pé ó ní láti jẹ́ pé àwọn Júù nípa tara tí wọ́n máa yí pa dà di Kristẹni tó bá fi máa di ọdún 1914 làwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì [144,000]. Àmọ́, lẹ́yìn ìgbà yẹn lọ́dún 1880, wọ́n gbé òye tuntun kan jáde tó sún mọ́ òye tá a ní nípa kókó yìí gan-an lónìí.