Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Láàárín ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn nìkan, àwa èèyàn Jèhófà ti mú àwọn ìtẹ̀jáde tó ń ṣàlàyé Bíbélì tó ju ogún bílíọ̀nù lọ jáde. Láfikún sí i, ní báyìí, ìkànnì wa jw.org, ti wà fún àwọn èèyàn tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó bílíọ̀nù mẹ́ta tó ń lọ sórí Íńtánẹ́ẹ̀tì kárí ayé.