Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ láwọn ọdún yẹn àti ọ̀pọ̀ ọdún lẹ́yìn náà, ka ìwé náà Jehovah’s Witnesses—Proclaimers of God’s Kingdom ojú ìwé 425 sí 520 (lédè Gẹ̀ẹ́sì), tó sọ̀rọ̀ nípa ohun tí iṣẹ́ ìkórè ṣàṣeparí rẹ̀ láti ọdún 1919 sí 1992.