Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Àpilẹ̀kọ yẹn sọ pé ọjọ́ ìbí Jésù táwọn kan sọ pé ó bọ́ sí ìgbà òtútù “ta ko ìtàn Bíbélì tó sọ pé àwọn olùṣọ́ àgùntàn wà níta pẹ̀lú àwọn agbo ẹran wọn.”—Lúùkù 2:8.