Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹjọ́ tó wáyé láàárín Arákùnrin Cantwell àti Ìpínlẹ̀ Connecticut ni àkọ́kọ́ nínú ẹjọ́ mẹ́tàlélógójì [43] tó wà ní Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti Ilẹ̀ Amẹ́ríkà, èyí tí Arákùnrin Hayden Covington bá wa bójú tó. Ó kú ní ọdún 1978. Ìyàwó rẹ̀, Dorothy, fi tọkàntọkàn ṣe aṣáájú-ọ̀nà déédéé títí tó fi kú ní ọdún 2015 lẹ́ni ọdún méjìléláàdọrùn-ún [92].