Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
f Ní bá yìí, gbogbo àwọn alàgbà ló ń jàǹfààní látinú ní Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Alàgbà Àtàwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́. Iye ọjọ́ tí wọ́n fi máa ń ṣe é yàtọ̀ síra, ọdún mélòó kan síra wọn ni ilé ẹ̀kọ́ yìí sì máa ń wáyé. Látọdún 1984, àwọn ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ ti ń gba ìdálẹ́kọ̀ọ́ nílé ẹ̀kọ́ yìí.