Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Àwọn òṣìṣẹ́ káyé àti àwọn tó yọ̀ǹda ara wọn máa ń lo èyí tó pọ̀ jù lára àkókò wọn lẹ́nu iṣẹ́ níbi tí wọ́n ti ń kọ́lé, àmọ́ wọ́n tún máa ń kọ́wọ́ ti ìjọ tí wọ́n ń dara pọ̀ mọ́ láti ṣe iṣẹ́ ìwàásù ní òpin ọ̀sẹ̀ tàbí ní ọwọ́ ìrọ̀lẹ́.