Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ohun tí orí yìí dá lé ni iṣẹ́ ìrànwọ́ tá à ń ṣe fún àwọn onígbàgbọ́ ẹlẹgbẹ́ wa tí àjálù bá. Àmọ́, lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà pàápàá máa ń jàǹfààní nínú rẹ̀.—Gál. 6:10.