Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Èyí ò túmọ̀ sí pé Sátánì ló ń darí àwọn tó ń sọ pé kó o má ṣe kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì mọ́. Àmọ́ Sátánì ni “ọlọ́run ètò àwọn nǹkan yìí,” àti pé “gbogbo ayé wà lábẹ́ agbára [rẹ̀].” Torí náà, kò yani lẹ́nu táwọn kan ò bá fẹ́ ká sin Jèhófà.—2 Kọ́ríńtì 4:4; 1 Jòhánù 5:19.