Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a O lè rí ìsọfúnni púpọ̀ sí i nípa bó o ṣe lè dáàbò bo àwọn ọmọ rẹ ní orí 32 ìwé Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà. Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà la ṣe é.