Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ó bọ́gbọ́n mu láti sọ pé àwọn èèyàn ń wo Ìsíkíẹ́lì bó ṣe ń ṣàfihàn àwọn àmì náà. Kí nìdí? Ìdí ni pé Jèhófà pàṣẹ ní tààràtà fún Ìsíkíẹ́lì pé “ìṣojú wọn” ni kó ti ṣe àwọn àmì kan, ìyẹn àṣefihàn nípa ṣíṣe búrẹ́dì àti gbígbé ẹrù.—Ìsík. 4:12; 12:7.