Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bí Jèhófà ṣe fàyè gbà á kí wọ́n pa Jerúsálẹ́mù run, kì í ṣe ìjọba ẹ̀yà méjì ti Júdà nìkan ni ìdájọ́ rẹ̀ dé bá, àmọ́ ó dé bá ìjọba ẹ̀yà mẹ́wàá pẹ̀lú. (Jer. 11:17; Ìsík. 9:9, 10) Wo ìwé Insight on the Scriptures, Ìdìpọ̀ Kìíní, ojú ìwé 462, lábẹ́ “Chronology—From 997 B.C.E. to Desolation of Jerusalem.”