ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

a Àwọn egungun tí Ìsíkíẹ́lì rí nínú ìran kì í ṣe tàwọn tí àìsàn tàbí ìjàǹbá pa tàbí tàwọn tó kú tìtorí ọjọ́ ogbó. Kàkà bẹ́ẹ̀, egungun náà jẹ́ ti àwọn ‘èèyàn tí wọ́n pa.’ (Ìsík. 37:9) “Gbogbo ilé Ísírẹ́lì” ni wọ́n pa lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ nígbà táwọn ọmọ ogun Ásíríà kó ẹ̀yà mẹ́wàá Ísírẹ́lì lọ sígbèkùn, táwọn ará Bábílónì sì kó ẹ̀yà méjì ti ilẹ̀ Júdà lọ sígbèkùn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́