Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọdún 29 Sànmánì Kristẹni ni tẹ́ńpìlì tẹ̀mí kọ́kọ́ wá sójú táyé, nígbà tí Jésù ṣèrìbọmi tó sì di Àlùfáà Àgbà. Ọ̀pọ̀ ọdún làwọn èèyàn fi pa ìjọsìn mímọ́ tì lẹ́yìn táwọn àpọ́sítélì kú. Àmọ́ látọdún 1919, ní pàtàkì, la ti gbé ìjọsìn mímọ́ ga.