Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ní Orí 5 ìwé yìí, a ti sọ̀rọ̀ nípa ìran tí Ìsíkíẹ́lì rí, èyí tó dá lorí àwọn ohun ìríra tí wọ́n ń ṣe nínú tẹ́ńpìlì.