Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Tó o bá fẹ́ mọ púpọ̀ sí i nípa ohun tí orúkọ Ọlọ́run túmọ̀ sí àti ìdí táwọn kan fi yọ orúkọ náà kúrò nínú Bíbélì tí wọ́n túmọ̀, wo Àfikún A4 nínú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun.