Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ní ẹ̀kọ́ 26 àti 27, a máa mọ ìdí tó fi pọn dandan pé kí ẹnì kan gba aráyé là àti bí Jésù ṣe gbà wá là.