Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nínú Bíbélì, “ìbáwí” máa ń gba pé kí wọ́n kọ́ ẹnì kan, kí wọ́n tọ́ ọ sọ́nà tàbí kí wọ́n ràn án lọ́wọ́ láti yí èrò tàbí ìwà rẹ̀ pa dà. Àmọ́ kò túmọ̀ sí pé kí wọ́n dá ẹni náà lóró tàbí hùwà ìkà sí i.—Òwe 4:1.