Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọdún 455 Ṣ.S.K. sí ọdún 1 Ṣ.S.K. jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin àti àádọ́ta ó lé mẹ́rin (454) ọdún. Ọdún 1 Ṣ.S.K. sí 1 S.K. jẹ́ ọdún kan (kò sí ọdún òfo). Bákan náà ọdún 1 S.K. sí 29 S.K. jẹ́ ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n (28). Àròpọ̀ gbogbo ẹ̀ wá jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́rin àti ọgọ́rin ó lé mẹ́ta (483) ọdún.