Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ni akoko ti Roy Ryan nṣe akọsilẹ awọn iriri igbesi-aye rẹ̀, ipo ilera rẹ̀ yipada bìrí si eyi ti ó burujai. Ó pari ọna igbesẹ rẹ̀ ori ilẹ-aye ni July 5, 1991, laipẹ pupọ si ìgbà ti ó kó ipa rẹ̀ gẹgẹ bi alaga ti ó maa nyika deedee nibi ijọsin owurọ ni Watchtower Farms.