Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Awọn kan ronu pe awọn ọrọ ti o wa ní Jakobu 5:14, 15 nii ṣe pẹlu imularada nipa ìgbàgbọ́. Ṣugbọn ayika ọrọ naa fihan pe Jakobu nihin-in ń sọrọ nipa aisan tẹmi. (Jakọbu 5:15b, 16, 19, 20) Oun gba ẹnikọọkan ti ó ti di aláàárẹ̀ nipa ìgbàgbọ́ niyanju lati kesi awọn alagba fun iranlọwọ.