Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ni December 13, 1992, nigba ti a ń pari ìtàn igbesi-aye yii, Arakunrin Tsatos sun ninu orun ikú.