ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé

b Ìwé-ìròyìn World Press Review ti November 1992 gbé ọ̀rọ̀-ẹ̀kọ́ kan jáde láti inú The Toronto Star tí ó sọ pé: “Ní àwọn ọdún mélòókan tí ó ti kọjá sẹ́yìn, àwọn ará Russia ti rí bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ìtànjẹ tí ó ti fìgbà kan rí dàbí aláìṣeégbébèéèrè dìde sí nípa ọ̀rọ̀-ìtàn orílẹ̀-èdè wọn tí ń di èyí tí kò lè dúró lójú àwọn òtítọ́. Ṣùgbọ́n ìsọdimímọ̀ nípa àjùmọ̀ṣiṣẹ́pọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì pẹ̀lú ètò-ìjọba kọmunist ni ó dúró fún ìyọnu àgbálù tí ń kódààmú báni jùlọ.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́