Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹ̀rí Bibeli àti ti ìtàn tọ́kasí ọdún 2 B.C. bí ọjọ́ ìbí Jesu Kristi. Nígbà náà, nítorí ìṣedéédéé, ọ̀pọ̀ yàn láti lo àmì náà C.E. (Sànmánnì Tiwa) àti B.C.E. (Ṣáájú Sànmánnì Tiwa), èyí sì ni ọ̀nà tí a gbà ń tọ́kasí àwọn ọjọ́ nínú àwọn ìtẹ̀jáde Watch Tower Society.