Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Awọn òjíṣẹ́ alákòókò kíkún ti awọn Ẹlẹ́rìí Jehofa ni a ń pè ní aṣáájú-ọ̀nà. Aṣáájú-ọ̀nà olùrànlọ́wọ́ kan ń lo ó kérétán 60 wákàtí ninu iṣẹ́-òjíṣẹ́ lóṣooṣù, aṣáájú-ọ̀nà déédéé kan ń lo 90 wákàtí, tí aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe sì ń lo 140 wákàtí.