Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Mishnah jẹ́ àkójọ àwọn àlàyé lórí ẹ̀kọ́ àwọn rabbi, tí a gbékarí ohun tí àwọn Júù kà sí òfin àtẹnudẹ́nu. A ṣàkọsílẹ̀ rẹ̀ ní apá ìparí ọ̀rúndún kejì àti apá ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀rúndún ìkẹta C.E., ó sì di ìbẹ̀rẹ̀ Talmud. Fún ìsọfúnni síwájú síi, wo ìwé pẹlẹbẹ náà Will There Ever Be a World Without War? ojú-ìwé 10, tí a tẹ̀jáde láti ọwọ́ Watchtower Bible and Tract Society of New York, Inc.