Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn àkíyèsí àwọn Masorete tí ó wà ní àlàfo ẹ̀gbẹ́ ìwé ni a ń pè ní Masora Kékeré. Àwọn àkíyèsí tí ó wà ní àlàfo ìwé ní òkè àti ìsàlẹ̀ ni a ń pè ní Masora Ńlá. Àwọn àkọsílẹ̀ tí a kọ sí apá mìíràn nínú ìwé àfọwọ́kọ náà ni a ń pè ní Masora Ìkẹyìn.