Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ ní ìrọ̀lẹ́. Ní ìbámu pẹ̀lú kàlẹ́ńdà wa, Nisan 14 yẹn jẹ́ láti ìbẹ̀rẹ̀ ìrọ̀lẹ́ Thursday, March 31, títí di ìgbà tí oòrun bá wọ̀ ní ìrọ̀lẹ́ Friday, April 1. A dá Ìṣe Ìrántí sílẹ̀ ní ìrọ̀lẹ́ Thursday, ikú Jesu sì ṣẹlẹ̀ ní ọ̀sán Friday ní ọjọ́ kan náà ti àwọn Júù. A jí i dìde ní ọjọ́ kẹta, ní kùtùkùtù òwúrọ̀ Sunday.