Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn orísun kan sọ pé Gàmálíẹ́lì jẹ́ ọmọ Hílẹ́lì. Talmud kò ṣe ṣàkó lórí ọ̀ràn yìí.