Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Ọ̀rọ̀ Hébérù náà fún “ẹ̀mí,” ruʹach, túmọ̀ sí “èémí” tàbí “atẹ́gùn.” Tí a bá lò ó fún ẹ̀dá ènìyàn, kò tọ́ka sí ẹ̀mí kan gédégbé tí ó dá nǹkan mọ̀ ṣùgbọ́n, kàkà bẹ́ẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ìwé atúmọ̀ èdè náà, The New International Dictionary of New Testament Theology, ṣe sọ ọ́, ó ń tọ́ka sí “ipá ìwàláàyè ẹnì kọ̀ọ̀kan.”