Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Nínú ìwé atúmọ̀ èdè náà, A Critical Lexicon and Concordance to the English and Greek New Testament, E. W. Bullinger ṣàlàyé pé, pa·rou·siʹa túmọ̀ sí ‘wíwà tàbí dídi ẹni tí ó wà níhìn-ín, nítorí náà, wíwà níhìn-ín, dídé; wíwá tí ó ní èrò bíbáni gbé fún ìgbà pípẹ́ láti àkókò dídé yẹn síwájú.’