Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ó lè jẹ́ èdè Hébérù ni a kọ́kọ́ fi kọ Ìhìn Rere Mátíù, pẹ̀lú ẹ̀dà kan tí a gbé jáde lẹ́yìn náà lédè Gíríìkì.