Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Kì í ṣe gbogbo òpìtàn ló fara mọ́ àwọn déètì àti bí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ kan ti ṣẹlẹ̀ tẹ̀léra nínú ìgbésí ayé Jerome.