Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nínú ẹ̀dà Septuagint ti Gíríìkì, ọ̀rọ̀ ìṣe kan náà táa tú sí “tọ́ sọ́nà padà” ló wà nínú Sáàmù 17[16]:5, níbi tí Dáfídì ti gbàdúrà pé kí àwọn ìṣísẹ̀ òun fẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin ní àwọn òpó ọ̀nà Jèhófà.