Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nígbà tí ojú ọjọ́ bá mọ́lẹ̀ kedere, a lè rí erékùṣù Kípírọ́sì láti Òkè Casius, tó wà ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn Áńtíókù.