Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Nínú àwọn ọ̀ràn kan, ohun tó ń fa àníyàn tàbí tó ń mú kí ó peléke ni àìsàn, irú bí akọ ìsoríkọ́.